HAPPY NEW MONTH!
Ẹ gbé ori nyin soke, ẹnyin ẹnu-na; ki a si gbé nyin soke, ẹnyin ilẹkun aiyeraiye: ki Ọba ogo ki o wọ̀ inu ile wa (Saamu 24:7).
Lift up your heads, O gates! And be lifted up, O ancient doors, that the King of glory may come in (Psalm 24:7).
Reti ise iyanu! Expect A Miracle!
Olorun yio bukun fun ọ - May God Bless You
Ayo Ni O - It is Joy.
留言