HAPPY NEW MONTH!
Nkan wọnyi ni mo ti sọ fun yin tẹlẹ̀, ki ẹyin ki o le ni alafia ninu mi. Ninu aiye, ẹyin o ni ipọnju; ṣugbọn ẹ tújuka; mo ti ṣẹgun aiye. (Johanu 16:33).
“I have told you these things, so that in me you may have peace. In this world you will have trouble. But take heart! I have overcome the world.”
(John 16:33).
Olorun yio bukun fun ọ - God Bless You
Ayo Ni O - It is Joy!
Reti ise iyanu - Expect A Miracle!
- EVANGELIST ADENIYI EKINE
Comments