HAPPY NEW MONTH!
Jesu si wò wọn o wipe, Eniyan ni eyi ko le ṣe iṣe fun, ṣugbọn ki iṣe fun Ọlọrun: nitori ohun gbogbo ni ṣiṣe fun Ọlọrun.
(Marku 10:27).
Jesus looked at them and said, 'With man it is impossible, but not with God. For all things are possible with God.'
(Mark 10:27).
Olorun yio bukun fun ọ - God Bless You
Ayo Ni O - It is Joy!
Reti ise iyanu - Expect A Miracle!
- EVANGELIST ADENIYI EKINE
Comentarios